Title: Welcome to today
1Welcome to todays service
Say to them that are of a fearful heart, be
strong, fear not, behold, your God will come with
vengeance, even God with a recompense he will
come and save you. Isaiah 35
21. Hymn 541 - Yoruba
- Mo ti sina, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku
fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. - Mo ti sonu, sinu ese, Ore Oluwa lori mi he,Oku
fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. - Halleluyah Halleluyah Ore Oluwa lori mi he,Oku
fun mi lori igi, Ore Ofe Oga Ogo poju. (Amin)
32. Hymn 387 Yoruba (117 Eng)
- Emi ba legberun ahon, Fiyin OlugbalaOgo Olorun
oba mi, Isegun Ore re cr Abi ko seun fun o, A
oma se fun mi Eje re se fun, Eje re se
fun mi. - Jesu to soro mi dayo, Omu banuje tanOrin yin
lenu elese, Iye ati ileracr Abi ko seun fun
o, A oma se fun mi. - Baba mi atOlorun mi, Fun mi ni ranwo ReKi nle
ro ka gbogbo aiye, Lola oruko Re cr Abi ko
seun fun o, A oma se fun mi. - O korin odi gbohun Re, A foju ri gbalaOniro
binuje yo ayo, Ara e ho fayo cr Abi ko seun
fun o, A oma se fun mi. (Amen)
4Three members prayers
- With God All Things Are Possible!
- -- Matthew 1926
53. Hymn 41 - English
- Holy Spirit the Comforter Descend into our
midstThou are the King of blessing We are
expecting thee. - For thou art the Almighty King Great King and
benefactorOh King of spirit descend now We
are expecting thee. - King of mercy descend now Look on us with
mercyWe thy children look unto thee Open thy
door of mercy.
- Oh Holy King, benefactor Father send us
blessingsFor thou art the Almighty Who
blesses His children. - King of mercy, O King of life Kindle thy light
for usThou art the King full of light We are
expecting thee. - O Holy King, O King of light Descend and bless
us nowFor thou art King of mercy We are
expecting thee. Amen.
6Silent Prayer
- Therefore I say to you, all things for which you
pray and ask, believe that you have received
them, and they will be granted you. - -- Mark 1124
74. Hymn 537 Yoruba
- Ma foya ni apa Jesu, Ko si ohun eru kan,Ina
ti njo ko le sun mo o, Ogun esu ti di wiwo
mole. - Mo ro mo agbelebu Re Mo ka ohun gbogbo
sasanMa beru ire okan mi, Ayo nbe ninu eje
Jesu.
- OVER -
84. Hymn 537 Yoruba (Contd)
- Emi ko ni ju o sile, Jesu Olugbala mi,Ninu Re
ni iye mi wa, Ire ni Olugbala mi. - Ijo Mimo bu si ayo, Oko iyawo wa pelu Re,Ayo
ni tire si ma yo, Ade iye na yio je tire.
Amin.
91st Bible Lesson
Beat your plowshares into swords And
your pruning hooks into spears Let the
weak say, "I am strong."' Joel 310
105. Hymn 52 Yoruba
- Oluwa Olugbala, Oluwa Olugbala, Jehovah
Olugbala, Yio si gbo ti wa. - Oluwa Oba Iye Oluwa Oba Iye, Kristi Oba
Imole, O mbe lodo wa.
- E kepe Oba Ogo, E kepe Oba Mimo, E kepe Oba
Iye Yio si gbo oro wa. - Oba ti ko gbagbe, Oba ti ko gbagbe,Oba ti ko
gbagbe, Ijo Mimo re.
- OVER -
115. Hymn 52 Yoruba
- Awon Angeli mbe, Awon Angeli mbe,Awon Angeli
mbe, Ninu ayo nla. - Iyin fun Oba Mimo, Iyin fun Oba nla,Ogo ni fun
Oba nla, Fun ise Re ni.
- E ke Halleluya, E ke Halleluya,E ke
Halleluya, Pelu ife Mimo. Amin.
122nd Bible Lesson
For it would have been better for them not to
have known the way of righteousness, than having
known it, to turn from the holy commandment
delivered to them. 2 Peter 221
136. Hymn 303 - Yoruba
- Eda to mola ko si, Eda to mola ko si,Eda to
mola ko si, Asan laiye nse. - Imo asan ni taiye, Imo asan ni taiye,Imo asan
ni taiye, Asan laiye nse. - Sagbeke le Oluwa, Sagbeke le Oluwa,Sagbeke le
Oluwa, Sagbeke re le. Amin.
14Church Announcements
15The Sermon
- That if you confess with your mouth,
- "Jesus is Lord," and believe in your heart that
God has raised Him from the dead, you will be
saved. -- Romans 109
16Collection
- Please remember
- All collections are taken ONCE, followed by
tithes and Chairmanship!
17Thanks Offering
- Enter into His gates with thanksgiving,
- And into His courts with praise.
- Be thankful to Him, and bless His name.
Psalms 1004
187. Hymn 406 - Yoruba
- Jehovah, Jesu Kristi, Michael Mimo, Oga
ogun,Ijo Mimo mbe niwaju Re, Teru tedun okan
wa,Lati saferi Emi Mimo, Ewa ogo Orun,Ibukun
ati gbega, Ma se fi du wa. - Ma bi si i, Si ma re si i, Ileri Re
fAbraham,Niwoyi odun titun, Iwo yio fomo se
re,Ileri yi fun Sarah, Jo muse fawon agan,Ti
nwon woju Re Baba, Fomo bIsaki.
- Ninu okun pupa ni, Farao atogun re,Parun
laigberi mo, Fun isimi okan Israel,Nigbati
reti dopin, Okun diyangbe ile,Nipa agbara
iyanu yi, Sin wa de nu iye. - Ogbon, Imo, Oye Re, Gegebi ti Solomon,Igbega
ati igbala Bi ti Josef, Danieli,Imisi a tohun
Orun, Bi ti Paul, Samueli,Elmorijah,
Olubukun, Se nwon ni ti wa.
- OVER -
197. Hymn 406 - Yoruba
- Awa nse ireti Re, Gege bOmo ileri,Ajo jumo
jogun iye, Ainipekun joba orun,Wa fEmi orun
satoko, Di wa lamure agbara,Ka sise
lailabawon, Si iye ainipekun. Amin.